Home ÀKỌ̀TUN Obìnrin kan lu ilé ìjọ́sìn ní jìbìtì Mílíọ̀nù Ọgọ́rùn-ún (N100M)
ÀKỌ̀TUN - iroyin - February 21, 2019

Obìnrin kan lu ilé ìjọ́sìn ní jìbìtì Mílíọ̀nù Ọgọ́rùn-ún (N100M)

Arabinrin omo odun mokandinlogoji, Iwuagwu Onyinyechi lo ti lo oruko MIA, ajo oluranlowo tii ki se ti ijoba. Ile-ijosin meta lo ti gba owo naa kaakiri ipinle Ogun ati Eko.
Ni kete ti o gba owo naa tan ni o ti poora bii iso sugbon “egberun Saamu ko le sa mo Olorun lowo” ni oro awon Olopaa. DSP Abimbola Oyeyemi ti ipinle Ogun ni ise opolo gidi ni awon se ki owo to te arabinrin naa.
DSP Oyeyemi ni ki awon ara ilu naa maa fi ara bale daadaa, ki won si maa wadii awon nnkan daju ki won to maa ro luu. O ni paapaa awon ile-ijosin wa gbogbo, o ni awon onijibiti mo pe ile-ijosin rorun lati lu jibiti nitori bi a se maa n mu esin bi igba ti a wa lodo Olorun gan-an. O ni iwadii to gbopan si n lo lowo nipa ibi ti arabinrin naa lo owo naa de.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…