Home ÀKỌ̀TUN Níbo ni bàbá sùwé wà?
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - February 18, 2019

Níbo ni bàbá sùwé wà?

Gbogbo awon ololufe Babatunde Omidina ti awon eniyan mo si Baba suwe ni wahala ti ba nipa aisan ojiji kan ti won lo ko luu.
Bi awon eniyan se n pe awon oniroyin ni won n pe gbogbo awon ore baba suwe naa.
Titi di asiko yii, opo wa ni ko tii mo ohun to sele pato si alagba naa. Awon kan lo ti n gbadun, gbogbo aago re ti IROYIN OWURO n pe ni ko loo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…