Ọjọ́ mẹ́ta ni mo fi sùn pápákọ̀ òfurufú – Mahmood Yakubu
Alaga ajo INEC ti ile wa ti gbogbo eniyan n da lebi lotun ati ni osi, ni iwaju ati ni eyin ni o ni ki awon eniyan jowo wo oun ati awon eniyan oun gege bi eleran ara.
O ni ki eti idibo yii le kese jari ti ko si ni si konu-n-ko-o ni ko je ki oun ati awon osise oun foju ba orun lati ojo keta si ojo Satide to ye ki eto idibo Aare waye.
O ni papako ofurufu ati ori irin ni awon ti n toogbe, ti ko si pe awon n sun nan apa ati ese ki eto idibo le kese jari. O ni bi eto idibo naa se sun siwaju ye Olorun nitori pe “riro ni ti eniyan.sise ni ti Olorun Oba”.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…