Home ÀKỌ̀TUN Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
ÀKỌ̀TUN - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - February 17, 2019

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu Abuja soro, nipa bi eto ibo se di sisun siwaju nitori awon idi pataki bii pinpin awon ohun elo idibo kaakiri ilu, yiyanju awon kaadi lori ero komputa INEC ati oju ojo ti ko dara to fun Baluu lati fo.
Gbogbo eyi ni Mahmood Yakubu salaye fun gbogbo omo Naijiria nibi ipade naa. Eyi si mu ki alaga agba fun egbe oselu APC, Adams Oshiomole ni gbogbo alaye INEC lo ye awon sugbon o si ye ki olori ajo naa toro aforiji gidi lodo omo Naijiria.
Eyi fa ariyanjiyan die nitori pe oniroyin kan naa ti beere eyi lowo olori ajo INEC. Mahmood Yakubu ni ede ni awon eniyan moo gbo ju ara won lo. O ni oun ti see loruko ajo naa ati oun gan-an. Gbogbo bi awon eniyan se lo Ojogbon naa nifun to, ko bebe ni ona ti gbogbo araye mo. O ni oun ti fi pari oro oun pe oun kabamo bi oro naa se ri ni igbeyin sugbon awon eniyan n reti e ma binu lati enu re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Yakubu the Yak, o dabo

Yakubu the Yak, o dabo Asiko niyi lati ki Yakubu Aiyegbeni pe o dabo o. Ti iku ko, ti arun…