Home orisiirisii Olùdíje dupò Ààrẹ tọwọ́ bọ̀’wé ìdìbò àlàáfíà
orisiirisii - Orisirisi - February 14, 2019

Olùdíje dupò Ààrẹ tọwọ́ bọ̀’wé ìdìbò àlàáfíà

Aare Mohammodu Buhari , Atiku Abubakar ati awon mokanlelaadorin miran ni won ti towo bo iwe adehun pe, ijongbon tabi idaluru kankan ko ni ti owo awon wa.
Won ni ko ni si wahala ni ibere ibo, aarin ibo ati leyin ibo. Gbogbo won towo bo iwe yii labe akose egbe alaafia kan ti Aare tele ri ni orileeede yii, Abudulsalam Abubakar dari.
Awon agbaagba yii je ki o ye gbogbo wa pe, enikeni to ba wole ibo naa gbodo je omo Naijiria. O ni omo iya kan naa ni gbogbo wa. Ko ye ki o si ogun tabi ote lati ibi kankan. Won ni gbogbo egbe oselu to wa lo je ti orileede yii nigba ti awon olutele won naa je omo orileede yii.
Awon alakoso ni kin wa ni a fe maa ba ara wa ja fun. Inu gbogbo omo Naijiria naa si dun nigba ti won ri Aare Muhammadu Buhari ati igbakeji Aare tele ri ni orileede yii, Alhaji Atiku Abubakar ti won n rerin si ara won. Iberu awon omo Naijiria naa ni awon egbe mejeeji to lokiki ju, egbe APC ati PDP. Nigba ti won si ti n feyin si ara won, a je wi pe ko ni si wahala Kankan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…