Home iroyin PDP n yo suti ete si APC lori oko ti won j ulu won ni Abeokuta
iroyin - Orisirisi - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - February 12, 2019

PDP n yo suti ete si APC lori oko ti won j ulu won ni Abeokuta

Yoruba bo won ni bi iya nla bag be ni sanle, kekere a maa gori eni.
Eyi lo difa fun egbe PDP to wa n fi apc se eleya bayii, latari bi awon kan se ju oko lu won ni Abeokuta lojo Monday.
PDP ni ko tan nidii won bi; o tun so pe awon to juko kan powe fun Aare Muhammadu Buhari pe ile to lo ni f. Won ni bi onile ba n fi apari isu han alejo, owe ile too lo lo n pa.
Ninu atejade kan ti agbenuso PDP, Kola Ologbodiyan, gbe sita, o ni oro ijoba APC tis u awon eniyan, to si je pe won ko fe won ni ijoba mo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…