Bill Clinton fagi le abewo to fe se wa si Naijiria
Aare ile Orile-ede Amerika tele, Ogbeni Bill Clinton, ti fagi le abewo to fe se wa si naijiria tele.
O ti gbro lati wa nibi ti awon oludije t fe buwo lu iwe alaafia, ko ma si jagidijagan lasiko ibo.
Sugbon o ti yi ero re pada.
O ni oun kowa mo nitori bi oun ba wa, oro oselu le fe ta ba ohun ti oun n bo wa se.
Bill Clinton ko sese maa wa si Naijiria tele.
Nigba to wa lasiko ijoba Obasanjo, o jo ijo King Sunny Ade lasso ti won se ape fun un.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…