Home orisiirisii Iléesẹ́ bàlúù Osinbajo sàlàyé ohun tó fa ìjàm̀bá
orisiirisii - Orisirisi - February 3, 2019

Iléesẹ́ bàlúù Osinbajo sàlàyé ohun tó fa ìjàm̀bá

Ileese caverton to n se baluu to gbe Ojogbon Yemi Osinbajo ni ki awon omo Naijiria ma se fi oro koro ko awon lorun. Won ni baluu daadaa ni baluu awon. Ko si le tete baje bi o ti wu ki eniyan loo to.
Won ni ohun to sele si eyi to gbe igbakeji Aare lo si ipinle Kogi to tuka nile ni nnkan se pelu oju-ojo ti ko dara. Won ni asiko ti a wa yii, oju ojo ti yato si ti tele. Bayii ile n pe ki o to moo ti o tumo si pe oru gun ju osan lo.
Ileese Caverton ni gbogbo eni to ba maa n fi idaji rin nile gan-an maa mo ohun ti awon n so yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…