Ìjọba àpapọ̀ àti Onnoghen jẹ̀bi – Femi Falana
Ejo ati itakuroso to n lo lowo ni orileede yii nipa olori eto idajo alagba Walter Samuel Onnoghen ni Alagba Femi Falana ti gbogbo aye mo si agbejoro agba ti kii fepo-foyo, ni ai-ba-won si nibe ni ai-ba won da sii.
O ni pelu bii ejo se ri yii, o ye ki ijoba apapo gba iwe ti won fi le Onneghen kuro lenu ise pada. Ki Onnoghen naa si se bi omoluabi, ki o kowe fi ise sile, ki o le gba gbogbo eto re gege bi o se wa labe ofin.
Onidajo yii ni iroyin gbee pe o ni apo ikowosi orisiirisii ti owo ile okeere si kun inu re bamu. Onidajo ko janpata nipa awon apo ikowosi naa. O ni loooto ni oun gbagbe lati koo si inu awon apo ikowosi ti oun jowo re fun ijoba nigba ti oun de ori aleefa.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…