Home orisiirisii Ẹ̀rù ń bà mí o – Gómìnà Ortom
orisiirisii - Orisirisi - January 28, 2019

Ẹ̀rù ń bà mí o – Gómìnà Ortom

Gomina ipinle Benue, Alagba Samuel Ortom lo maa figbe bonu fun awon oniroyin ni osan oni. O ni gbogbo ibi ti oun ba rin si ni oun ti n ri owo pe a won kan n lepa emi oun.
O ni ko si oun ti oun ni ki awon eniyan ma se se, o ni aabo awon ara ilu oun lo je oun logun ju. O ni ariwo yii lo dabi eni pe o n bi ijoba apapo ninu ti won fi n lepa oun. O ni won koko de awon ajo EFCC si oun ti won ko si ka ebo mo eru oun.
O wa gba awon ara ipinle naa ni imoran pe ti iku ba pa oun bayii ki won mu ijoba apapo daadaa nitori pe gbogbo ibi ti oun ba rin si ni oun ti n ri owo pe awon kan n lepa emi oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…