Home iroyin Won ni ara iyawo Buhari ko ya
iroyin - Orisirisi - January 27, 2019

Won ni ara iyawo Buhari ko ya

Bi ipolongo ibo se n lo, orile-ede Germany ni a gbo pe Iyaafin Aisha Buhari, eni to je iyawo Aare Muhammadu Buhari, wa bayii, nibi to ti n gba itoju.
Iwe iroyin alatagba ‘The Cable’ se alaye pe ailera naa ni ko je jki o maa wa nibi awon ipolongo ibo Aaare, paapaa ti awon obinrin to n dari.
Bi o tile je pe eni kan ko so pato pe ara Aisha fa, ti Akowe Iroyin re, Suleiman Haruna, naa si so pe oun ko ni oro lati so lori re, eni kan too sun mo Aare gbongbon so ni bonkele peara Aisha ko le.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…