Home iroyin Paga! Dokita oyinbo ku si oteeli
iroyin - Orisirisi - January 25, 2019

Paga! Dokita oyinbo ku si oteeli

Kayefi nla n se awon olopaa ati dokita ni Ipinle Edo bayii, latari bi dokita kan, se ku iku ojiji ni oteeli kan.
Won ko tii mo ohun to gbe dokita naa lo si oteeli naa, bee won to ti mo ohun to pa a.
Ile iwosan olukoni ti University of Benin Teaching Hospital ni oloogbe naa ti n sise ki olojo to de.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…