Idi ti mo fi da adajọ agba duro – Buhari
Aare Muhammadu Buhari ti se alaye idi to fi da Adajo Agba ni Naijiria, Alagba Walter Onnoghen, duro, to si fi Adajo Ibrahim Tanko se adele.
Oni ni Buhari gbe igbese kabiti naa, to si ti da opo awuyewuye sile.
Buhari ni opo ejo to ba de iwaju Onnoghen lo maa n se bo se wu u, to si je pe o maa n tu awon to ba se ibaje to han saye sile.
Bakan naa, o ni ase ti ile ejo Code of Conduct Tribunal pa ni oun tele.
Opo eniyan lo gba pe ajo Code of Conduct Tribunal ko lase lati se igbejo esun aikede dukia ti won fi kan Onnoghen.
Koda, ile ejo kotemilorun ni Abuja so pe ki ajo CCT o sinmido na.
Sugbon Buhari so pe o to gee fun Onnoghe.
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…