Home iroyin Bi mọ tiẹ rina ri ẹni ti yoo wọle ibo, n ko nii sọ – Abiara
iroyin - Orisirisi - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - January 25, 2019

Bi mọ tiẹ rina ri ẹni ti yoo wọle ibo, n ko nii sọ – Abiara

Oludasile soosi CAC Agbala Itura, Pastor S. K. Abiara, ti so pe oun kii se ojise Olorun to maa n soro boroboro.
O ni oun kii maa so asottele laulau bi awon kan se maa n so.
Nigba to n soro lori eto kan lori telifisan LTV lale ojo Alamisi, o ni bi oun tie mo eni to maa wole laarin awon oludije ibo to n bo, bii Aare Muhammadu Buhari ati Alhaji Atiku Abubakar, ikun oun lo maa wa.
Bakan naa, o ni adura bi alaafia yoo se maa joba ni oun maa n gba.
O ni oun ko si lara awon eniyan to maa n daya ja ara ilu nipa siso pe itajesile n bo niwaju.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…