Home iroyin Awon nnkan marun-un ti o ko mo nipa Guru Maharaji Ji
iroyin - Orisirisi - January 25, 2019

Awon nnkan marun-un ti o ko mo nipa Guru Maharaji Ji

Lolade Ogunbowale

Guru Maharaji je omo Naijiria ti o wa lati Ipinle Oyo, ni ilu Ibadan.
O je olori elesin emi ti oruko esin naa jee One Love Mission tabi Divine Love Family.
O je eni ti o maa n fi awon omoleyin ree yagan.
O so wi pe oun ni Abgara lati segun oniruru aisan ati lati fi opin si ogun to ma n ja awon eniyan.
Sibesibe, bi o se ma pon ara re le, ti o ba wa ninu isoro kan, ko ni je ki o re oun lati ma le je ki ise iranse re ma gboro sii.
Awon nnkan marun-un nipa Guru Maharaji ji
Ikini. Oruko re gangan je Mohammed Ajirobatan Ibrahim. Awon om leyin re maa n pe e ni jesu dudu. O n gbe ni Ibadan, ipinle Oyo.
Ikeji. Ni ilu oba ni London ni Guru Maharaji ji ti ka iwe re, leyin naa ni o da esin naa kale ninu Osu beelu ni odun 1987. O so pe oun gbo ipe naa nigba ti o si n kawe ni U.K ni odun 1954.
Gege bi o ti so, o ni ise ti a fi ran oun ni lati yo awon omo Naijiria kuro ninu ise ati iya.
Iketa. O ni oun jeri si ise Olorun ti a ko le ri ninu aye.
Ikerin. Guru Maharaji ni tempili eyi ti awon olujosin ree maa ti lo n josin, eyi ti won pe ni Satguru Maharaji Ji ti o wa ni ona masose Eko si Ibadan.
Ikarun-un. Nigbati Guru Maharaji Ji so asotele re fun odun 2019, o ni oun mo eni ti o ma gbegba oroke ninu idibo ti Aare to n bo lona.
O so wi pe, Aare Muhammadu Buhari ni o ma wole.
O si so pe awon ti inu won o dun si asotele naa, pe ki won wa ba oun lati mo nnkan to ma se e si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…