Wara maalu dara fun iwosan diabetes
Lolade Ogunbowale
Awon oniwadii ijinle ti gbe iwe kan kale ti a pe ni (African Journal of Traditional, Complementary and Alternative Medicine).
Ninu iwe naa ni won ti so wipe wara ti maalu ni awon ohun isaraloge bii insulin tii o maa dekun diabetes ati awon ohun imiran bii oju fifo, aitete jinna egbo, ati wahala kidirin.
Wara maalu o ni ko ni ora cholesterol to po, bee ko ni sugar lapoju.
Dipo bee, o ni pupo mineral ati vitamin C, B2,A ati E.
Ninu iwadi ti a se, a ri wipe wara maalu da fun eniti o ma n tete re ati eni ti ago ara re o mokun daadaa (weak immune system).
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…