PDP Ondo: Ile gba asia oludije kuro lowo Bode Ayorinde
Lolade Ogunbowale
Iroyin to n to wa leti bayii ni pe Ile ejo agba ti ilu Akure ti gba ipo lowo Ogbeni Bode Ayorinde to n lo fun ipo ile igbimo asofin tii Owo Ose federal constituency.
Ile ejo so pe, Sadiq Obanoyen nii eni tii o ni ipo naa, nitori pe oun ni o gbe igba oroke ninu idibo ibo abele primary.
Ile ejo naa so wi pe ko bojumu fun awon olori egbe PDP lati ma fun ajo INEC ni oruko Obanoyen gege bi eni ti egbe PDP faa kale.
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…