Home iroyin Ajeju ogede maa n fa wahala ba ara
iroyin - January 23, 2019

Ajeju ogede maa n fa wahala ba ara

Lolade Ogunbowale

Awon onimo ijinle ti se ikilo pe ajeju ogede maa n fa sisanraju, wahala okan, atogbe, ki nnkan ma su si eniyan lara, ori fifo ati bebelo.
Awon onimo ounje naa wipe ki a ma je koja ogede marun-un ni ojojumo.
Won ni sibesibe awon ohun isaraloge wa ninu ogede jije sugbon ti o ba ti di ajeju, o man fa nnkan mi sinu ago ara.
Won se alaye pe ninu ogede kan, a le ri to eya ara ora 105 calories, metadinlogun iwon giraamu carbohydtares, giraamu meta fiber ati bi metadinlogun sugar pelu awon ohun isaraloge miran. Ti a ba je o maa n se ago ara ni anfanni amo ti o ba ti di ajeju, oma n fa aisan si ara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…