Home LÁGBO ÀRÍYÁ Idi ti n kii lo si soosi – Falz
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - January 19, 2019

Idi ti n kii lo si soosi – Falz

Akorin igbalode kan, Folarin Falana, ti adape re n je Falz, ti se alaye idi ti kii fii lo si ssosi lenu ojo meta yii.
Gege bi o se so, o ni oju ti maa n wa lara oun ju ni soosi.
O ni oro naa le debi pe awon oluso agutan tabi pasito gan-an maa n foju si oun lara, ti won yoo si maa gbe oun gege.
O ni eyi ko ye ko ri bee tori bakan naa ni gbogbo wa ri niwaju Olorun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…