Home LÁGBO ÀRÍYÁ Adekunle Gold fe ba Sunny Ade se kolabo
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - January 19, 2019

Adekunle Gold fe ba Sunny Ade se kolabo

Leyin ti Adekunle Gold ti gbe olowo ori re, Simi, niyawo bayii, ohun kan to wa lokan re ni ko ba agba oje ninu ise orin, King Sunny Ade, se kolabo, iyen ki won jo korin po ninu awo orin kan naa.
O ni opo eniyan lo ti maa n so pe oun fi orin jo akorin nla ti a n pe ni KSA.
O ni inu oun naa dun de idi lojo kan ti oun ati Sunny Ade pade, ti baba naa si bere sii ko orin oun.
Adekunle Gold so ninu iforowanilenuwo kan to se pelu iwe iroyin ‘Saturday Punch’ pe oun to ku lokan oun ni ki oun ni anfaani lati ba Sunny Ade se kolabo naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…