Ilé-ẹjọ́ gba ìyọ̀ǹda Dino Melaye
Ile ejo giga to fi ikale si ilu Abuja ti beere fun iyonda Seneto Dino Melaye ti awon olopaa lo fi owo sinkun ofin mu laipe yii.
Adajo ni ki awon olopaa je ki ara Melaye ya daadaa ki o to wa bere si ni maa je ejo re. Adajo ni “oku o ki n sin oba” ati wi pe ipo Melaye ga ni ilu ju ki o wa maa jejo ninu aga awon ti eya ara pe nija lo.
Ile ejo gba akowe agba ile igbimo asofin ati elomiran to ni ile gidi ni ilu Abuja gege bi oniduro fun Dino Melaye.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…