Home orisiirisii Àsírí ojúbọ àwọn ajínigbé tú l’Ékìtì
orisiirisii - Orisirisi - January 18, 2019

Àsírí ojúbọ àwọn ajínigbé tú l’Ékìtì

Owo awon olopaa ipinle Ekiti ti te awon meji kan ti won si fi oruko bo lasiri lati le fi owo sinkun ofin mu awon to ku. Won fo ojubo won tutu, won si ko gbogbo awon ere ati owo ayederu ti ile yii ati ti ile okere.
Opopona Ado si Ilawo ni abule ti won ti n se ise ibi naa wa. Iwadii ati itani-lolobo lo tu asiri naa. Gbogbo igba ni ariwo ajinigbe tabi omo sonu n sele ni ipinle naa.
Ti a ko ba gbagbe, ose to koja naa ni igbakeji gomina ipinla naa, Ogbeni Egbeyemi kede ki awon soja dakun pada si awon opopona ati gbogbo bode to wo ilu naa.
Iwadii to gbopon si n lo lowo lati le foju awon asebi naa han nile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…