Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Goolu Ronaldo fun Juventus ni ife ẹyẹ
ERÉ ÌDÁRAYÁ - January 17, 2019

Goolu Ronaldo fun Juventus ni ife ẹyẹ

Bi awon alase egbe agbaboolu Juventus se gba Christiano Ronaldo lodun o lo ti so eso rere fun won o.
Lojo Alaaruba, o se won lore kan to joju.
Oun lo gba ami ayo eyo kan soso ti won fi na AC Milan ninu idije Italian Super Cup, ti Juventus sig be ife eye naa lo sile.
Pelu idunnu ni Ronaldo naa se soro nipa aseyori naa.
Se alangba to be sile lati ori igi iroko, o ni bi eni kan ko yin oun, oun a yin ara oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…