Home iroyin Ile ejo tun da yeepe si gaari Ladi Adebutu ni Ipinle Ogun
iroyin - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - January 16, 2019

Ile ejo tun da yeepe si gaari Ladi Adebutu ni Ipinle Ogun

Nigba to ye ki oludije ipo gomina ninu egbe PDP ni Ipinle Ogun, Senito Ladi Adebutu, maa yo pe wahala ti Senito Buruji Kashamu n ba a fa ti fe di oun igbagbe, ile ejo giga ni Abuja tun ti da wahala si i lagbada.
Ile ejo giga Abuja ni bi won se yan an ni oludije ko tona rara.
Funra re naa lo gbejo lo si kootu, tori o fe ki awon ba oun gba Kashamu sgbe kan.
Ohun to wa pani lerin die ni pe ni nnkan bii ose kan si ojo idajo yii ni Kashamu n so pe ki awon darapo lona alaafia ninu egbe PDP ni Ipinle Ogun.
Koda, iroyin ko tan kanle pe o so pe oun setan lati gba Adebutu laye ki o je oludije ni.
Sugbon ojo keta loun naa tun ni oun ko so bee, oun kan n soro irepo ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…