Home LÁGBO ÀRÍYÁ Eedris Abdukareem fi epe sin Oga olopaa Ibrahim Idris jade
LÁGBO ÀRÍYÁ - January 16, 2019

Eedris Abdukareem fi epe sin Oga olopaa Ibrahim Idris jade

Opolopo omo Naijiria ni ko soro Oga Olopaa agba to sese lo, Alagba Ibrahim Idris, daadaa o.
Bi awon egbe oselu alatako se n dunnu pe o fipo sile ni awon omo Naijiria kan naa n so pe Olorun lo baa won le e lo.
Ni ti akorin aorosoboto, Eedris Abdukareem, owe nla,tbi ko jo epe ko jo adua, lo pa mo Idris lonii.
O ni oun ko ni sepe, oun ko ni sure.
O ni to ba se pe daadaa ni oga olopaa naa se fun Naijiria, ki daadaa ko maa ba a bo se feyin ti yii.
O ni sugbon to ba je pe aburu lo se fun Naija, ki aburu naa maa je tie.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…