Home LÁGBO ÀRÍYÁ Antar Laniyan fe dabira, sugbon owo n s’ojoro
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - January 13, 2019

Antar Laniyan fe dabira, sugbon owo n s’ojoro

Owo ni bi oun ko ba si nile, ki enikeni ma se da imoran kanak leyin oun.
Ki owe yin maa je ti agba osere, Antar Laniyan.
O ti so ohun kan to joba lokan re bayii ti o fe se, sugbon ti sengi ko tii si lati se e.
O ni nibi ti oun ba ise tiata ati fiimu de bayii, o wu oun lati ko ile iwe kan ti won ti le maa ko awon eniyan, paapaa awon odo langba, ni bi a se n se ise naa.
O ni kinni naa wa lokan oun gidi sugbon ko si owo lati se e.
Antar Laniyan ni ohun ti opo eniyan maa n ro pe awon osere lowo lowo ko ri beee rara.
O ni to ba je laarin awon Ibo ni, awon to lowo maa n ran awon to ba ni ero ati ato gidi lowo.
Sugbon laarin awon Yoruba, oro ko fi bee ri bee.
O wa so pe oun si gba pe Olorun a gbe oluranwo dide lori erongba okan re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…