Kashamu jebure, o pari ija pelu Adebutu
Senito Buruji Kashamu ti jebure awo olugbebe ni Ipinle Ogun bayii, tori o ti pari surutu pelu Senito Ladi Adebutu to n gbe apoti ibo gomina fun egbe PDP nibe.
Bi o tile je pe ejo si n lo ni kootu, tori Kashamu naa fe gbe apoti, o ti jawo nibe, to si so fun awon omoleyin re ki won dibo fun Adebutu.
O ni oun se eyi ki alaafia le job, ki ilosiwaju si ba egbe PDP.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…