Home LÁGBO ÀRÍYÁ Iyabo Ojo, Ronke Oshodi Oke gbadura ilera fun MC Oluomo
LÁGBO ÀRÍYÁ - January 11, 2019

Iyabo Ojo, Ronke Oshodi Oke gbadura ilera fun MC Oluomo

Awn osere fiimu Yoruba ti fihan pe iba iponju las more o.
Won ko gbagbe oore ti yoga onimoto, MC Oluomo, maa n se fun won.
Nipa bee, peel bi o se wa ni osibitu lasiko yii, lori bi won kan se gun un lobe niga ti ida be sile nibi ipolongo ibo won egne apa ni Eko, won alariya naa ko se bi alaigbo.
Meji ninu won, Iyabo Ojo ati Ronke Oshodi Oke, ti ki okunrin naa pe o pele, ti won si ba a dupe lowo Olorun pe oro naa ko ju bee lo.
Won wa se e ni adura pe ki alaafia tete pada si ago ara re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…