Home iroyin Awon eniyan nla nla n wo lo ki MC Oluomo ni osibitu
iroyin - Orisirisi - January 11, 2019

Awon eniyan nla nla n wo lo ki MC Oluomo ni osibitu

Iyi ti okan lara won öga onimoto ni Eko n, Alhaji Musiliu Akinsanya, ti won n pe ni MC Oluomo, ni lara tubo n po si ni o, pelu bi awon kan se gun un ni obe lojo Isegun.
Nibi wahara ti awon kan da sile lasiko ipolongo ibo gomina APC ni ijamba naa ti sele, to si je pe eni kan, Ismail Afeez, gba ibe rorun.
Ile iwosan Eko Hospital, to je ti alada ala, ni Ikeja, ni won ti n toju MC Oluomo, ti a si gbo pe o sesee ki won tansukua re lo si oriel-ede Amerika.
Iroyin fi yeni pe awon oloselu nla ala ti awon eeyan j-n-kan-ja-n-kan miran lo n lo se abeto si, se Yoruba bo, won ni ile oba to jo, ewa lo bu kun un.
Moto olopaa big marun-un ni won lo ro wawa niwaju osibitu naa, tori partake ti won kan Oluomo si – se orujo lo ro amo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…