Home iroyin Koko Zaria ni ko siku loju MC Oluomo
iroyin - Orisirisi - January 9, 2019

Koko Zaria ni ko siku loju MC Oluomo

Okan lara awon gbajumo oga onimoto ni Eko, Koko Zaria, ti fowo soya pe ko si iku loju oga oun, MC Oluomo, eni to wa ni osibitu bayii, leyin ti won gun lobe ni orun ati ikun lanaa.
Isele naa se nigba ti egba APC n se ipolongo ibo ni Eko.
O ni awon ota kan n gbiyanju lasan lori Olu Omo ni, sugbon imoran won ko ni jo.
Koko Zaria pa a lowe pe ipo nla kan n be niwaju ti won n ba Olu Omo ja le lori, sugbon oun naa ni yoo lo ipo naa bi won fe bi won ko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…