Eewo! Won gun MC Oluomo lobe nibi ipolongo ibo APC!
Nnkan nla sele lonii nigba ti egbe APC n bere ipolongo ibo gomina fun Alagba Jide Sanwo-Olu.
Nigba ti ipolongo ibo naa n pari lo, ti Gomina Ambode n soro lowo ni laasigbo naa bere.
Koda, won ni Wasiu Ayinde n korin lasiko naa.
Eni kan ko mo ibi ina ti ru wa, ti ija bere, ti onibon n yobon, ti aladaa si n yo ada.
Awon eniyan bii mejo la gbo pe won gun lobe, ti won si ni gbajugbaja oga onimoto, Alhaji Musiliu Akinsanya, MC Oluomo, si wa nibe.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…