Arun asthma ati iba lo se Melaye – Awon olopaa
Awon dokita osibitu olopaa ti won ti n toju Senito Dino Melaye ti se alaye lori aisan to n se e.
Won ni nigba ti won gbe e de odo awon, won ri i pe o ni wahala arun aile mi daadaa, ti awon oyinbo n pe ni asthma, to si je pe o tun ni eje ruru – hypertension.
Sugbon sa o, won ni ara re ti ya debi pe o le jejo nile ejo.
Idi niyi ti won fi fe gbe e lo si Lokoja, lati lo jejo lori esun ti won fi kan an pe o mo nipa bi won se yin olopaa kan nibon ni nknan bii osu mefa seyin.
Sugbon sa o, Melaye so pe ara oun ko tii ya ati pe oun ko tii ni agbara lati lo sejo kankan.
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…