Home LÁGBO ÀRÍYÁ ‘Inu ala ni Olorun ti so fun mi pe Funke Akindele ni iyawo mi’
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - January 6, 2019

‘Inu ala ni Olorun ti so fun mi pe Funke Akindele ni iyawo mi’

Baale Funke Akindele, Bello Rasheed, ti so pe inu ala ni Olorun ti koko so fun oun pe awon maa di tokotaya.
O ni odun mefa seyin ni oun koko lala ri Funke.
O ni sugbon oun ko ka oro naa kun tele.
O fi kun un pe nigba ti oun tun so fun Funke, ko ka oro naa si koko.
Okunrin ti won tun n pe ni JJC fi kun un pe ose kan pere ni ede awon ko yede mo.
Sugbon o ni nigba to ya, adehun Olorun se lori awon.
Ose to lo ni Olorun fi ibeji lanti-lanti jinki won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…