Home iroyin Guru Marahaji ni Buhari ni yoo wole
iroyin - January 5, 2019

Guru Marahaji ni Buhari ni yoo wole

Bi oniruuru awon wolii se n so ohun ti won ri lori ibo to n bo lona, baba ti a mo si Guru Marahaji naa ti so tie.
O ni Aare Muhammadu Buhari ni yoo wole.
O ni ifihan t oun ni ko gbe ade le Alhai Atiku Abubakar lori.
O ni Buhari ti se daadaa, o si letoo lati se eleekeji.
O wa ro Atiku ati awon yoku ti won n ba a du ipo naa ki won e atileyin fun un.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…