Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Fanikayode fi epe buruku banu lori Dino Melaye
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - January 5, 2019

Fanikayode fi epe buruku banu lori Dino Melaye

Minisita fun Oro Oko Ofurufu tele, Oloye Femi Fanikayode, ti fi epe bonu lori oro senito Dino Melaye ti awon olopaa n ba fa surutu lowo.
O tun ranti ti okunrin gbenugbenu kan, Ogbeni Deji Adeyanju, ti oun naa n ba ijoba jejo.
O ni nitori pe onigbagbo ni awon mejeeji ti won sim aa n gbadura, aye awon to ba fe tiwon je lo maa baje.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…