Home iroyin Adigunjale meji gba idajo iku
iroyin - January 5, 2019

Adigunjale meji gba idajo iku

Ile ejo kan ni ilu Akure ti dajo iku fun awon adigunjale meji kan, Tobechukwu Aguonu ati Uche Igwe.
Adajo Fasanmi ni won ni lati ku tori bi won se gba moto ati awon ohun ini miiran lowo Alagba Augustine Okolie ninu odun 2016.
O ni awon olopaa fi idi esun naa mule, tie bi eni ti won ja lole naa si so hulehule oro.
O fi kun un pe moto naa ti won ri ni Ipinle Anambra fihan pe loooto ni won jebi idigun jale.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…