Ààrẹ Goodluck Jonathan ló gbà mí sísẹ́ – Amina Zakari
Arabinrin Amina Zakari ti awon egbe oselu ni awon ko faramo ko wa ninu awon oga fun ajo INEC gege bi Mahmood Yakubu se yan-an. Arabinrin naa ti bo sori afefe lati salaye ara re nigba ti oga INEC pata-pata naa salaye pe ko tan mo Aare Buhari.
Amina Zakari ni omo ipinle Jigawa ni oun nigba ti Aare Buhari wa lati ipinle Katsina. O ni Aare Goodluck Jonathan ni o yan oun si ipo ajo INEC ti ko si sebo leru oun. O ni oun tun sise pelu Aare Olusegun Obasanjo ti ko tun si wahala Kankan.
Arabinrin yii ni oun gbo ti awon kan n so pe oun se mago-mago ninu ibo gomina to waye ni ipinle Osun, o ni eni to ba ni eri to daju ki o jade.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…