Home iroyin Oku eniyan le tente sori Odo Osun
iroyin - January 3, 2019

Oku eniyan le tente sori Odo Osun

Awon eniyan Osogbo foju ri kayeefi lanaa Alaaruba nigba ti okun okunrin kan le tente lori Odo Osun.
Awon olugbe agbegbe kan ti won n pe ni Osunjela so pe lati ooro Alaaruba ni awon ti ri oku naa nibe.
Won o mo bo se je, sugbon won ni o jo pe okunrin na jin sodo nigba to lo we ni tori won ri aso to bo si eti odo.
Sugbon sa o, awon ajo agbofinro Civil Defence ni awon ti gbo nipa re ati pea won yoo seto lati lo gbe e kuro nibe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…