Home orisiirisii Ilé-ẹjọ́ da ẹjọ́ Melaye nù
orisiirisii - Orisirisi - January 3, 2019

Ilé-ẹjọ́ da ẹjọ́ Melaye nù

Awon agbejoro Seneto Dino Melaye ti gba ile-ejo lo lati le je ki awon olopaa kuro ni ile re. Ile-ejo ni ko si eni to ga ju ofin lo. Ile-ejo ni gbogbo eni ti won ba fesu ipaniyan kan lo letoo lati lo salaye ara re.
Eyi lo mu ki ile-ejo da ejo Melaye nu bii omi isanwo ni ojo keje ti awon olopaa ti yi ile naa ka. Gbogbo ogbon ete ti Melaye lo ni ko dabi eni pe o fe sise lodo awon olopaa ni ote yii. O ti ba ileese telifison kan soro pe oun ko si nile ati ni ilu Abuja, o ni ti oun ba ti de ni oun maa yoju si awon olopaa naa sugbon awon olopaa di”Akintola taku” si agbegbe naa.
Opo igba ni ikolura ti n waye pelu awon olopaa ati Melaye ti awon nnkan to jo bii ere ori itage ko ni je ki ejo naa lese nile mo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…