Home iroyin Awon ajinigbe: Fayemi pase ki won ge gbogbo igbo eba ona
iroyin - January 3, 2019

Awon ajinigbe: Fayemi pase ki won ge gbogbo igbo eba ona

Gomina Ipinle Ekiti, Dokita Kayode Fayemi, ti pase pe ki won ge gbogbo igbo to wa leba awon popona ilu naa.
O se eleyii tori awon ajinigbe ti won n sa pamo kaakiri ni.
Lasiko ti won n se eto adura odun ni ile ijoba ni Fayemi so oro yii, to sir o awon eniyan pe ki won maa ta ijoba lolobo logan ti won ba kefin awon eniyan buruku.
Igbakeji gomina, Alagba Bisi Egbeyemi, lo fi ise Fayemi je nibi eto naa, ti awon eniyan nla nla miiran, bii aya gomina, Erelu Bisi Fayemi, naa si wa nibe.
Bi a ko ba gbagbe, Fayemi dun opo osise ijoba ninu lasiko odun tori o san lara owo osu ti gomina ana, Ayodele Fayose, je won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…