Home Orisirisi Afaa Salaudeen fipa ba omo odun marun-un lo po
Orisirisi - January 3, 2019

Afaa Salaudeen fipa ba omo odun marun-un lo po

Okunrin aafaa kan to tun je olukoni eko Islam (Islamic Studies teacher), Abdulsalam Salaudeen, ni esin re ti tu bayii, nigba ti won ri fidio ibi to ti n ba omodebinrin kan se isekuse.
Koda, omo odun marun-un pere ni omo naa, ti Salaudeen si n fi nnkan re e nidii.
Nomba 16, Awoyemi Street, ni Igando Road, Ikotun, niluu Eko ni Salaudeen n gbe.
Eni kan to ka a mo ibi to ti n huwa aito lo dogbon ya fidio naa, to si mu u lo sodo awon olopaa.
Nigba ti Salaudeen gan-an ri fidio naa, o kan bu sekun gbagada ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…