Home Orisirisi A kò gbẹ́sẹ̀ lé kọ̀ǹténà 40 tó ní owó dọ́là nínú – Customs
Orisirisi - January 3, 2019

A kò gbẹ́sẹ̀ lé kọ̀ǹténà 40 tó ní owó dọ́là nínú – Customs

Awon ajo Customs orileede yii ti ogbeni Joseph Attah gbenu soro fun ni ki awon eniyan lo sora gidi nipa oro siso. O ni iroyin ti tan kaakiri paapaa julo lori ero ayelujara pe awon gbese le dola owo orileede Amerika ti o kun inu oko oju omi kontena.
Attah nii loooto ni awon gbese le ogoji kontena to kun fun oogun ti ijoba apapo ni ko gbodo wole bii Tramadol ati awon oogun fun inira lorisiirisii lo kun inu kontena naa.
Oga Customs yii ni ohun to sele ko ju bee lo. Ko si owo kankan nibe. O si `tun ro awon ara ilu ki won ma se da ogun tabi idaluru sile rara. O ni ki won maa se iwadii ohun gbogbo daju ki won to maa gbe iroyin kiri.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…