Home iroyin Ojú àwọn alágbèrè yóò já a lọ́dún yìí – DK Olukoya
iroyin - Orisirisi - January 2, 2019

Ojú àwọn alágbèrè yóò já a lọ́dún yìí – DK Olukoya

Olori ijo Mountain of Fire and Miracle Ministries, Alagba Daniel Olukoya, ti kilo fun awon alagbere pe ki won jawo, tori ti won ko ba jawo, won a kandin niyo lodun yii.
Ninu asotele re fun odun yii, Olukoya ni Olorun setan lati ran awon angeli oran si awon alagbere.
O ni won ni anfaani lati yipada, yala awon olomoge ati odomokunrin ti won ko tii se igbeyawo ni o, tabi awon to ti se be, sugbon ti won tun n yan ale kiri.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…