Home orisiirisii Iná sọ ní ìjọba ìbílẹ̀ Ọlọ́rundá, Òṣogbo
orisiirisii - Orisirisi - January 2, 2019

Iná sọ ní ìjọba ìbílẹ̀ Ọlọ́rundá, Òṣogbo

Ijamba ina dede so ni deede aago mejo koja iseju meedogun ni ile ise ijoba ibile Olorunda ti o wa ni Osogbo tii se oluulu ipinle Osun.
Titi di asiko ti a n ko iroyin yii jo, ko tii si eni to le so iye nnkan ti ina naa ti baje nitori pe awon osise pana-pana ilu Osogbo si n ba ina naa ja lowo. Igba ti o ya, omi ti awon pana-pana gbe wa tan , won si sare wa omi lo lati fi pana naa.
Ki Eledua ba wa fi ofo ra emi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…