Home LÁGBO ÀRÍYÁ Omọ Seun Kuti dara pọ mọ awon onijo Egypt 80

Omọ Seun Kuti dara pọ mọ awon onijo Egypt 80

Omo ajanaku kii yara, omo t’ekun ba bi, ekun ni yoo jo.
Ki owe yii maa je ti idile ogbologbo akorin, Oloogbe Fela Anikulapo-Kuti.
Meji ninu awon omo re, iyen Femi ati Seun Kuti, ni won ti di gbajugbaja akorin afro.
Sugbon Seun tun f’oba le e loru ojo Isegun, nigba ti omobinrin re ti ko tii ju eni odun merin lo, darapo mo lori itage, to si n jo pelu awon obinrin judi-judi ti won maa n jo pelu awon idile afro.
Kii se pe omo naa kan jo die bi omode, o dara po mo egbe akorin Seun Kuti and the Egypt 80 Band ni, ti oun naa si n ju iwonba idi ti Olorun fun un.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…