Home LÁGBO ÀRÍYÁ OLF dari Olamide pada s’ọdọ Ambode
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - January 1, 2019

OLF dari Olamide pada s’ọdọ Ambode

Leyin ohun ti awon eniyan kan wo gege bii iyapa laarin Gomina Akinwunmi Ambode ati ilumomika akorin to n je Olamide, osere naa dara po mo awon akegbe re nibi ere ipari odun One Lagos Fiesta, ti ijoba Ambode se agbekale re.
Olamide sun mo gomina naa daadaa tele, ti Ambode si feran re gidi, debi pe ko le ma korin nibi awon eto ti ijoba Eko ba n se.
Sugbon nigba ti awon alase egbe APC ni Eko ni awon ko ni je ki Ambode se gomina leekeji, odo won ni o jo pe Olamide fidi si.
Koda, o sere fun Alagba Babajide Sanwo-Olu, lasiko ti oun Ambode n koju ara won.
Sugbon oju tun rinju loru ojo kinni osu kinni odun yii, nigba ti Olamide naa sere ni Victoria Island, nibi ti Ambode naa wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…