Home iroyin Ija ile mu ki ilu Offa ati Erin Ile maa taun sira won
iroyin - Orisirisi - December 31, 2018

Ija ile mu ki ilu Offa ati Erin Ile maa taun sira won

Ijoba Ipinle Kwara gbodo tete petu si ija kan to n ru laarin ilu Offa ati Erin Ile o.
Lati opo odun seyin ni ilu mejeeji ti n ja si ile, latari pe awon kan fun awon kan nile, I awon kan si ni ko ri bee mo.
Ija na tun ru jade latari idajo ile ejo agba – Supreme Court – kan, ti awon Erin Ile ni o ti so ile naa di ti awon.
Sugbon awon Offa ni ko ri bee, won ni idajo naa ko fun Erin Ile ni ile naa.

Bayii, Olori agbajo awon omo ilu Erin Ile, Alagba Samuel Alabi; ati akegbe re ni Offa, Alhaji Najim Yassin, ni won n se abenugan lori aawo naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…