Buhari ki omo Naijiria ku odun
Aare Mohammadu Buhari ti ki awon omo Naijiria ku odun tuntun o. O ni inu oun dun lati se ‘Happy New Year’ pelu won, to si se ileri pe oun yoo tubo sise takuntakun lati rip e iderun wolu.
O ran won leti ibo to n bo, o si se ileri pee to idibo naa ko ni ni eru ninu.
O ni oun ko mu eto idibo naa ni pami-n-ku, ti oun yoo si je ki nnkan lo wooro ati alaafia.
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…