Home iroyin Won ni awon olopaa ti ja ina ile Melaye
iroyin - December 30, 2018

Won ni awon olopaa ti ja ina ile Melaye

Oro Senito Dino Melaye ati awon olopaa da bii igba ti ologbon mei ba njo n je iyan, ti won n fi obe osiki je e . Awon agbaagba bo, won ni omo tooro lasn ni yoo ku nigbeyin.
Bi iku ba si n de dede, dede naa a maa deku.
Dino Melaye so pe oun ko si ninu ile re ni Abuja, nibi ti awon olopaa duro si lati mu u lo si ago won.
Koda, o ni oun ko si ni Abuja.Sugbon awon olopaa ko gba bee, won nigbagbo pee jo lowo ninu.
Idi niyi ti won fi ja ina oba to wo inu ile naa.
A gbo pe won se eyi ki inira le ba a to ba je pe o wa ninu ile, ki o le adeb ii okete ti won fin mo inu isa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…