Home Orisirisi O se! Odo awon Boko Haram ni Leah Saribu tun ti maa se odun tuntun
Orisirisi - December 30, 2018

O se! Odo awon Boko Haram ni Leah Saribu tun ti maa se odun tuntun

Ti ise iyanu kankan ko ba sele lonii si ola, agodo awon alakatakiti Boko Haram ni omo ile iwe kan, Leah Saribu, yoo tun ti se odun tuntun o.
Lati nnkan bii odun kan ni awon Boko Haram ti mu omobinrin jojolo naa sodo, tori ko gba fun wn lati so o di elesin Musulumi.
Iya omo naa ke gbajare lojo Jimoo, to n so pe ki ijoba Buhari jowo se gbogbo ohun to ba wa ni ikapa re ki omo oun le wale.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…